C.A.C ILÉ-Ẹ̀KỌ́ ỌJỌ́ ÌSINMI FUN OṢÙ KÍNNÍ SI OṢÙ KẸFÀ, 2021 : Àkòrí Gbòòrò: ỌLỌ́RUN NÍNÚ ÌṢÀKÓSO ÈNÌYÀN (II)

By | January 14, 2021
C.A.C ILÉ-Ẹ̀KỌ́ ỌJỌ́ ÌSINMI FUN OṢÙ KÍNNÍ SI OṢÙ KẸFÀ, 2021 : Àkòrí Gbòòrò: ỌLỌ́RUN NÍNÚ ÌṢÀKÓSO ÈNÌYÀN (II)
  
ÌJỌ ÀPỌ́SÍTÉLÌ KRISTI
Ní Àgbáyé
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ ILÉ-Ẹ̀KỌ́ ỌJỌ́ ÌSINMI
Àkòrí Gbòòrò:
ỌLỌ́RUN NÍNÚ ÌṢÀKÓSO ÈNÌYÀN (II)
OṢÙ KÍNNÍ SI OṢÙ KẸFÀ, 2021
 
ITỌKA
ISỌRÍ KÍNNÍ: ÌṢÀKÓSO KÈFÈRÍ ṢÁÁJÚ ÌGBÈKÙN
 
1. January 24 Àti 31, 2021 – Gbogbo Ọkàn Pátápátá Tí Ọlọ́run Ní Wọn Ń Ṣe
2. February 7 Àti 14, 2021 – Ọlọ́run Ń Ja Fún Ẹtọ Àwọn Júù Àti Ti Àwọn Kèfèrí
3. February 21 Àti 28, 2021 – Ọlọ́run Nínú Ìṣàkóso Egipti
4. March 7 Àti 14, 2021 – Ọlọ́run Safihàn Títóbi Julọ Rẹ Láàrin Àwọn Kèfèrí.
 
ISỌRÍ KEJÌ: ÌṢÀKÓSO KÈFÈRÍ NÍ ÀKÓKÒ ÌGBÉKUN ÀTI LẸ́YÌN ÌGBÉKUN
 
5. March 21 Àti 28, 2021 – O Gbé Àwọn Orílẹ̀ Ede Dìde Lòdì Sí Àwọn Ènìyàn TíRẹ.
6. April 4 Àti 11, 2021 – Ọlọ́run Ní Bábílónì
7. April 18 Àti 25, 2021 – Ọlọ́run Fi Àmì Òróró Yàn Kírúsì Kèfèrí.
8. May 2 Àti 9, 2021 – Ọlọ́run Ní Páṣíà
 
ISỌRÍ KẸTA: NÍNÚ JÉSÙ ÀTI ÌJỌ
 
9. May 16 Àti 23, 2021 – Ọna Ìṣàkóso Jésù Ti O Pé
10. May 30 Àti June 6, 2021 – Ọlọ́run Nínú Ètò Ìṣèlú Sẹnturi Kínní
11. June 13 Àti 20, 2021 – Ìṣàkóso Ìjọ Àkọ́kọ́.
12. June 27, 2021 – Ìjọba Ọlọ́run Ní Igbẹyin Lórí Gbogbo Ẹ̀dá.
 
ÀWỌN ÌṢẸ́ MÍRÀN
 
1. June 28, 2021 – July 17, 2021 – Ṣíṣẹ Bí O Ti Ń Dúró
2. July 4, 2021 Àti July 11, 2021 – Agbeyẹwo
3. July 18, 2021: – Ìdánwò Ìjọ Kọ̀ọ̀kan
4. Àwọn Ẹ̀kọ́ Tí Ìjọ Àpọ́sítélì Kristi Gbagbọ Nínú Rẹ
5. Orin Ilé Ẹ̀kọ́ Ọjọ Ìsinmi
6. Kalenda

Leave a Reply