CAC LIVING WATER DAILY DEVOTIONAL FOR SEPTEMBER 17, 2022 : TOPIC – NO VACUUM IN LIFE

By | September 18, 2022

CAC LIVING WATER DAILY DEVOTIONAL FOR SEPTEMBER 17, 2022 : TOPIC – NO VACUUM IN LIFE

READ PREVIOUS CAC DEVOTIONALS HERE

LIVING WATER CAC DAILY DEVOTIONAL GUIDE

Sunday, September 18, 2022.

Wife Appreciation Day

NO VACUUM IN LIFE

Read: Judges 4:1-16

[1]And the children of Israel again did evil in the sight of the LORD, when Ehud was dead.
[2]And the LORD sold them into the hand of Jabin king of Canaan, that reigned in Hazor; the captain of whose host was Sisera, which dwelt in Harosheth of the Gentiles.
[3]And the children of Israel cried unto the LORD: for he had nine hundred chariots of iron; and twenty years he mightily oppressed the children of Israel.
[4]And Deborah, a prophetess, the wife of Lapidoth, she judged Israel at that time.
[5]And she dwelt under the palm tree of Deborah between Ramah and Bethel in mount Ephraim: and the children of Israel came up to her for judgment.
[6]And she sent and called Barak the son of Abinoam out of Kedeshnaphtali, and said unto him, Hath not the LORD God of Israel commanded, saying, Go and draw toward mount Tabor, and take with thee ten thousand men of the children of Naphtali and of the children of Zebulun?
[7]And I will draw unto thee to the river Kishon Sisera, the captain of Jabin’s army, with his chariots and his multitude; and I will deliver him into thine hand.
[8]And Barak said unto her, If thou wilt go with me, then I will go: but if thou wilt not go with me, then I will not go.
[9]And she said, I will surely go with thee: notwithstanding the journey that thou takest shall not be for thine honour; for the LORD shall sell Sisera into the hand of a woman. And Deborah arose, and went with Barak to Kedesh.
[10]And Barak called Zebulun and Naphtali to Kedesh; and he went up with ten thousand men at his feet: and Deborah went up with him.
[11]Now Heber the Kenite, which was of the children of Hobab the father in law of Moses, had severed himself from the Kenites, and pitched his tent unto the plain of Zaanaim, which is by Kedesh.
[12]And they shewed Sisera that Barak the son of Abinoam was gone up to mount Tabor.
[13]And Sisera gathered together all his chariots, even nine hundred chariots of iron, and all the people that were with him, from Harosheth of the Gentiles unto the river of Kishon.
[14]And Deborah said unto Barak, Up; for this is the day in which the LORD hath delivered Sisera into thine hand: is not the LORD gone out before thee? So Barak went down from mount Tabor, and ten thousand men after him.
[15]And the LORD discomfited Sisera, and all his chariots, and all his host, with the edge of the sword before Barak; so that Sisera lighted down off his chariot, and fled away on his feet.
[16]But Barak pursued after the chariots, and after the host, unto Harosheth of the Gentiles: and all the host of Sisera fell upon the edge of the sword; and there was not a man left.

MEMORISE: In the days of Shamgar, son of Anath, In the days of Jael, the highways were deserted… until I, Deborah, arose; arose a mother in Israel (Judges 5:6,7).

EXPOSITION
There is a saying that “there is no vacuum in life”. The role played by Deborah in our text gives credence to this assertion. The people had forsaken the LORD as usual and chosen a foreign god, instead. The Living God, God of their fathers, had in turn “sold them” to their enemies. But under the ministry of Deborah, they had realised their sin and thereby turned back to their true Source. God then arose to deliver them by the ministry of a woman. But if we may ask, all this while, where were the men of Israel at that time?

God can never be without a witness in any generation. If anyone refuses to go for God, He has 7000 to replace only one fatigued Elijah (1 Kgs. 19:1-18). Don’t feel too important and indispensable. Deborah who was a mother in Israel and the wife of Lappidoth, even as today is Wife Appreciation Day, was ready to go when most men were not willing, for fear. God can use anythi…
[10:13 pm, 17/09/2022] Devotional Sen: ÌJỌ APOSTELI KRISTI
Naijiria àti Oke Okun

OMI IYE NAA
…ti o ni ipa rere lórí ayé ènìyàn

OṢÙ KEJE – OṢÙ IKEJILA 2022

Ọjọ́
Ọjọ Aiku
Sunday,
September 18, 2022.
Ayajọ Imọriri Ìyàwó

Ka
Àwọn Onidajọ 4:1-16

AKỌSORI
Ni ọjọ Ṣamgari ọmọ Anati, ní ọjọ Jaeli, àwọn ọna opopo dá, àwọn èrò si n rin ni ọna ikọkọ… títí èmi Debora fi dìde, tí èmi dìde bí iya ni Israẹli (Àwọn Onidajọ 5:6,7).

ÀKÒRÍ: KO SI AAYE TI O ṢÒFÒ NÍNÚ AYÉ

ITUPALẸ
Ọrọ kan wa ti àwọn ènìyàn máa ń sọ pé, “Ko si ààyè tó ṣòfò nínú ayé mi”. Ipa tí Debora kó ni ibi kika wa tonii jẹri ọrọ yii. Àwọn ènìyàn náà ti kọ OLÚWA silẹ gẹ́gẹ́ bí ìṣe wọn, wọn si ti yàn ọlọrun àjèjì dípò Rẹ. Ọlọ́run Alààyè náà, Ọlọ́run àwọn baba wọn, tí ta wọn tí mọ ẹṣẹ wọn, wọn si ti yipada si orísun wọn. Ọlọ́run wa dìde láti gba wọn la nípasẹ̀ ìṣẹ-iranṣẹ obìnrin. Ṣùgbọ́n bí a o ba béèrè, láti ìgbà yii wa, nibo ni àwọn ọkùnrin Israẹli wa ni akoko náà?
Ọlọ́run ko le ṣalai ni ẹlẹ́ri/aṣojú ni ìran kankan. Bí ẹnikẹ́ni ba kọ láti tọ Ọlọ́run lẹ́yìn, o ni ẹgbẹ̀rún méje láti rọ́pò Èlíjà tí o ti ṣaarẹ (I A. ỌBA 19:1-18). Máṣe ro pe ó ṣe pàtàkì julọ tàbí o jẹ kòṣeemani. Debora to jẹ iya ni Israẹli àti aya Lapidotu, bí oni tí jẹ Ayajọ Ọjọ Mimọriri Àwọn Aya, ṣetan láti lọ nígbà tí ọ̀pọ̀ ọkùnrin ko ṣetan, nítorí ibẹru Ọlọ́run le lo ohunkóhun, ẹnikẹ́ni ní igbakuugba. Ko le si ààyè to ṣòfò nínú ayé, yálà nípa tẹmi tàbí nípa tara. Ìpèsè Ọlọ́run yóò mú ẹni/ohun kan wá láti dúró ní ààyè náà. Kọ́ bí a ti ń diwọ fún Ọlọ́run nínú ìṣẹ́ yòówù tó bá fún ọ láti ṣe.
Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀da Bíbélì Vulgate tí ṣàpèjúwe rẹ̀: ” Ọlọ́run yàn àwọn ogun tuntun miiran, Òun fúnra Rẹ si wó ẹnu ọna ọta palẹ”. Jẹ ẹda tuntun fún Olúwa lonii, kí o si dúró ní ipo oore-ọ̀fẹ́ tí a fi ọ si gan-an nínú ìfẹ́ pípé Rẹ. A gbàdúrà pé gbogbo wa yóò wúlò, a o si ṣe e sinmile fún Ọlọ́run ni orúkọ Jésù. Àmín.

ÀWỌN KÓKÓ ÀDÚRA
1. Oluwa, dárí ẹṣẹ iyèméjì, aifẹ ṣíṣẹ, igbọjẹgẹ àti ilọra mi nínú ṣíṣe àwọn ojúṣe mi ji mi.
2. Gbàdúrà pé ipo rẹ ko ni i ṣòfò fún aiwulo.
3. Báwi, fi ré, kí o si kọ ohun gbogbo to wa ninu rẹ to le mú ki o kùnà kí o si ṣubú, ní orúkọ Jésù Kristi.

ORIN FÚN ONI: I.O. CAC
923

Àfikún Ibi Kika Fún Òní: Amosi 6 – 9; Obadiah 1

Leave a Reply